factograf
YO

Baruch Spinoza

Baruch Spinoza

Key facts

ọjó ìbí24 Oṣù Bélú 1632
ọjó ikú21 Oṣù Èrèlè 1677
kẹ́ẹ̀kọ́ níLeiden University
ìlú ìbíAmsterdam
All data from the card 7
Orúkọ
Baruch de Spinoza
Ìbí
Oṣù Kọkànlá 24, 1632Amsterdam, Dutch Republic
Aláìsí
February 21, 1677 (ọmọ ọdún 44)The Hague, Dutch Republic
Ìgbà
17th-century philosophy
Agbègbè
Western Philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́
Rationalism, founder of Spinozism
Ìjẹlógún gangan
Ethics, Epistemology, Metaphysics

Baruch Spinoza (Hébérù: ברוך שפינוזה‎ Baruch Shpinoza, Pọrtugí: Bento de Espinosa, Látìnì: Benedictus de Spinoza) to di Benedict Spinoza (November 24, 1632 – February 21, 1677) je omo Portogi ara Hollandi elesin Ju amoye. Pelu opolo onisayensi to ni, bi ise Spinoza se lagbara to ati se pataki to ko han titi ki o to ku. Loni, o je gbigba bi ikan ninu awon aselaakaye olokiki imoye orundun 17k, to se ipilese fun Olaju orundun 18k ati iseagbewo bibeli odeoni. Nitori iwe re Ethics, to jade leyin iku re, ninu ibi to ti lodi si iseonimeji okan-ara Descartes, Spinoza je gbigba bi ikan ninu awon amoye pataki ninu Imooye apaiwoorun. Amoye ati akoitan Georg Wilhelm Friedrich Hegel so nipa gbogbo awon amoye igbalode pe, "E le je Asespinosa tabi ki e mo je amoye rara."


Read next

In 123 languages

Text from Wikipedia, CC BY-SA 4.0 · Source article