factograf
YO

Ice Cube

Ice Cube

Key facts

ọjó ìbí15 Oṣù Òkúdu 1969
iṣẹ́ oòjọ́ rẹ̀Songwriter, òṣèré
ìlú ìbíLos Angeles
All data from the card 10
Orúkọ àbísọ
O'Shea Jackson
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi
Cube, Don Mega
Ọjọ́ìbí
15 Oṣù Kẹfà 1969Los Angeles, California
Ìbẹ̀rẹ̀
South Central Los Angeles, California, U.S.
Irú orin
Hip hop, gangsta rap, political hip hop
Occupation(s)
Rapper, actor, film director, screenwriter
Years active
1984–present
Labels
Priority (1987–1996)Lench Mob (1994–present)EMI (1987–present)
Associated acts
N.W.A, C.I.A., Scarface, Da Lench Mob, Westside Connection, Public Enemy, WC and the Maad Circle, Snoop Dogg Boo-Yaa T.R.I.B.E.
Website
icecube.com

O'Shea Jackson (ojoibi June 15, 1969), to gbajumo pelu oruko ori itage re Ice Cube, je rapper, osere, olukowe-ere, oludari filmu, ati atokun. O bere ise orin re gegebi ikan ninu awon omo egbe olorin hip-hop C.I.A. ati leyin re o di omo egbe olorin rap N.W.A. Leyin igba to fi N.W.A sile ni December 1989, o bere ise idakorin to yorisirere, ati bi olukowe, oludari, osere ati atokun sinema. Bakanna, o ti se bi ikan ninu awon atokun awon ere ori telifisan Showtime tounje Barbershop ati ti ori telifisan TBS tounje Are We There Yet?, awon mejeeji ti won da lori awon filmu to se bi osere.



Read next

In 81 languages

Text from Wikipedia, CC BY-SA 4.0 · Source article