factograf
YO

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Zelda Williams

Zelda Williams

Key facts

ọjó ìbí31 Oṣù Agẹmọ 1989
iṣẹ́ oòjọ́ rẹ̀òṣèré, òṣeré fíímù
ìlú ìbíNew York
All data from the card 4
Ọjọ́ìbí
Zelda Rae Williams31 Oṣù Keje 1989New York City, U.S.
Iṣẹ́
Actressdirectorproducerwriter
Ìgbà iṣẹ́
1994–present
Parents
Robin Williams (father)Marsha Garces Williams (mother)
Zelda Williams (2011)
Zelda Williams (2011)

Zelda Rae Williams (tí a bí ní Oṣù Keje Ọjọ́ ọ̀kàn-lé-lọ́gbọ̀n, ọdún 1989) jẹ́ Òṣèré ará ìlú Amẹ́ríkà kan, Olùdarí, Olùgbéjáde, àti Òǹkọ̀wé. Ó jẹ́ ọmọbìnrin sí òṣèré àti apanilẹ́rìn-ín Robin Williams àti Olùgbéjáde fíìmù àti aláàánú Marsha Garces Williams. Gẹ́gẹ́ bí òṣèré ohùn, ó jẹ́ olókìkí jùlọ fún fífọ́ ohùn Kuvira nínú eré ọmọdé Nickelodeon, The Legend of Korra.


Read next

In 54 languages

Text from Wikipedia, CC BY-SA 4.0 · Source article