factograf
YO
Sign in

The Croods

All data from the card 14
Adarí
Chris Sanders Kirk DeMicco
Olùgbékalẹ̀
Kristine Belson Jane Hartwell
Àwọn òṣèré
Nicolas Cage Emma Stone Ryan Reynolds Catherine Keener Cloris Leachman Clark Duke
Orin
Alan Silvestri
Ìyàwòrán sinimá
Roger Deakins
Olóòtú
Erika Dapkewicz Darren T. Holmes
Ilé-iṣẹ́ fíìmù
DreamWorks Animation
Olùpín
20th Century Fox
Déètì àgbéjáde
Oṣù Kejì 15, 2013 (Berlin) Oṣù Kẹta 22, 2013 (UnitedOrílẹ̀ èdè America)
Àkókò
98 iṣẹju
Orílẹ̀-èdè
USA
Èdè
Gẹ̀ẹ́sì
Ìnáwó
$135–175 milionu
Owó àrígbàwọlé
$587.3 milionu

The Croods jẹ́ eré àgbéléwo tí ó ní n ṣe pẹ̀lú eré ìdárayá. ó jẹ́ eré àgbéléwò tí a yà ní orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òṣèré tí ó kópa nínú rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà bakan nan-an.

Àwọn òṣeré fílmù

  • Emma Stone gẹ́gẹ́ bí Eep Crood
  • Nicolas Cage gẹ́gẹ́ bí Grug Crood
  • Ryan Reynolds gẹ́gẹ́ bí Guy
  • Catherine Keener gẹ́gẹ́ bí Ugga Crood
  • Clark Duke gẹ́gẹ́ bí Thunk Crood
  • Cloris Leachman gẹ́gẹ́ bí Gran
  • Randy Thom gẹ́gẹ́ bí Sandy Crood
  • Chris Sanders gẹ́gẹ́ bí Belt

Àjápọ̀ òde

  • Official website
  • The Croods, (IMDb) (Gẹ̀ẹ́sì)

Read next

In 64 languages

Text from Wikipedia, CC BY-SA 4.0 · Source article