factograf
YO

Sam Smith

Sam Smith

Key facts

ọjó ìbí19 Oṣù Ẹ̀bibi 1992
iṣẹ́ oòjọ́ rẹ̀olórin
ìlú ìbíLọndọnu
All data from the card 8
Ọjọ́ìbí
Samuel Frederick Smith19 Oṣù Kàrún 1992London, England
Iṣẹ́
Singer songwriter
Ìgbà iṣẹ́
2008–present
Awards
Full list
Irú orin
Pop R&B soul
Instruments
Vocals
Labels
Capitol
Website
samsmithworld.com

Samuel Frederick Smith (tí a bí ní 19 May 1992) jẹ́ akọrin àti aṣẹ̀dá orin ọmọ orílè-èdè England. Lẹ́yìn tí ó di olókìkí ní oṣù kẹwàá ọdún 2012 nípasẹ̀ ìṣàfihàn rẹ̀ nínú orin àdákọ tí àkọ́lé rè ń jẹ́ " Latch ", èyí tó ṣipò kọkànlá lórí atọ́ka Singles UK. Wọ́n sì padà ṣàfihàn orin "Naughty Boy" tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "La La La" tó ṣịpò kìíní lóṣù karùn-ún, ọdún 2013. Ní oṣù kejìlá ọdún 2013, wọ́n yan Smith fún àmì-ẹ̀yẹ Brit Critics Choice Award, ti ọdún 2014, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ méjèèjì.

Read next

In 66 languages

Text from Wikipedia, CC BY-SA 4.0 · Source article