factograf
YO

Mir

Mir
All data from the card 16
NSSDC ID:
1986-017A
Call sign:
Mir
Crew:
3
Launch:
1986–1996
Launch pad:
LC-200/39, and LC-81/23, Baikonur CosmodromeLC-39A,Kennedy Space Center
Reentry:
2001-03-2305:50:00 UTC
Mass:
124,340 kg(274,123 lbs)
Living volume:
350 m³
Perigee:
385 km (208 nmi)
Apogee:
393 km (212 nmi)
Orbit inclination:
51.6 degrees
Orbital period:
88.15 minutes
Orbits per day:
16.34
Days in orbit:
5,519 days
Days occupied:
4,592 days
Number of orbits:
c.86,331

Mir ni ibudo-oko lofurufu to je ti Sofieti ko to di ti Rosia. Ohun ni o je ibudo lofurufu ibi isewadi akoko lagbaye ti awon eniyan gbe ninu re fun ojo pipe, o si tun je akoko iru iran eketa awon ibudo-oko lofurufu, won bere sii ko lati 1986 de 1996 pelu awoda modular. Ibudo oko yi sise fun odun medogun titi di March 23, 2001, nigbati won moomo mu kuro loju ona-iyipo re, ki o to ja si wewe ninu ipadawole si ojuorun lori Guusu Okun Pasifiki.




Read next

In 84 languages

Text from Wikipedia, CC BY-SA 4.0 · Source article