factograf
YO
Sign in

Lagos Lagoon

Lagos Lagoon
All data from the card 10
Location
Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Coordinates
6°30′06″N 3°31′21″E / 6.5015814°N 3.5224915°E
Lake type
lagoon
Basin countries
Nàìjíríà
Max. length
50 km
Max. width
13 km
Surface area
6,354.7 km²
Surface elevation
0 m
Islands
Lagos Island, Victoria Island
Settlements
Èkó

Lagos Lagoon jẹ́ omi ọ̀sà tí ó bá Ìlú Èkó jorúkọ. Orúkọ yìí jẹ́ orúkọ Àgùdà tí ó túnmọ̀ sí "Omi ńlá" ní Èdè Àgùda, nítorí èyì "Lagos Lagoon" jẹ́ àpẹrẹ orúkọ ìbálú jórúkọ.

Ìrísí rẹ̀

Gígùn ọ̀sà yìí ju àádọ́ta kìlómítà lọ, ó jìnà sí òkun pẹ̀lú fífè méjì sí márún, tí ó sì ní irà lẹ́bá etí ọ̀sà. Fífẹ̀ rẹ̀ tó bíi 6,354.7 km². Ọ̀sà yìí tòrò níwọ̀nba, tí àwọn ọkọ̀ ojú omi nla tó ń gba ojú òkun kìí dàárú.

Ọ̀sà yìí jápọ̀ mọ́ Odò Ògùn àti Odò Ọsun.


Àwọn àwòrán rẹ̀

Lagos Lagoon, Nigeria
Lagos Lagoon, Nigeria
Lagos Lagoon, Nigeria
Lagos Lagoon, Nigeria
Lagos Lagoon
Lagos Lagoon
Lagos Lagoon
Lagos Lagoon
4 images

Read next

In 15 languages

Text from Wikipedia, CC BY-SA 4.0 · Source article