factograf
YO

Genzebe Dibaba

Genzebe Dibaba
All data from the card 8
Ọjọ́ìbí
8 Oṣù Kejì 1991Chefe, Bekoji, Arsi Province, PDR Ethiopia
Height
168 cm
Weight
52 kg
Orílẹ̀-èdè
Ethiopia
Erẹ́ìdárayá
Women's Sport of athletics
Event(s)
1500 metres, 3000 metres, 5000 metres
Team
NN Running Team (2023–)
Coached by
Tolera Dinka

Genzebe Dibaba Keneni ni a bini ọjọ kẹjọ, óṣu February, ọdun 1991 jẹ elere sisa lóbinrin ilẹ Ethiopia to da lori arin ati ọna jinjin.

Àṣèyọri

Ni ọdun 2008, Genzebe yege ninu idije agbaye U20 to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti silver ninu mita ti ẹgbẹrun maarun. Lati ọdun 2009 de 2017, Genzebe kopa ninu idije agbaye to si tun kopa ninu àṣèkagba awọn ere sisa naa. Ni ọdun 2010, Dibaba kopa ninu idije agbaye U20 lẹlẹkeji to si gba wura ni mita ti ẹgbẹrun maarun. Ni ọdun 2014, Dibaba ni a peni elerelobinrin ti Laureus fun ọdun naa. Ni ọdun 2015, Dibaba jẹ elere sisa lobinrin ti IAAF agbaye ti ọdun naa. Ni ọdun 2015, Genzebe kopa ninu idije agbaye ti mita ti ẹgbẹrun maarun to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti idẹ ati wura ninu ayẹyẹ naa. Ni ọdun 2016, Genzebe kopa ninu Olympics ti Rio to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti silver ni mita ti ẹgbẹrun kan ati aadọrun.

Read next

In 39 languages

Text from Wikipedia, CC BY-SA 4.0 · Source article