Vanuatu ( vah-noo-AH-too or van-WAH-too), ni onibise bi orile-ede Olominira ile Vanuatu, je orile-ede erekusu to budo si Guusu Okun Pasifik. Ile arkipelago, to wa lati ileru, je bi 1,750 kilometres (1,090 mi) si ilaorun apaariwa Ostrelia, 500 kilometres (310 mi) si ariwailaorun Kaledonia Tuntun, iwoorun Fiji, ati guusuilaorun awon Erekusu Solomoni, leba Guinea Tutun.
